Tẹsalonika Keji 3:3 BM

3 Ṣugbọn olódodo ni Oluwa, òun ni yóo fi ẹsẹ̀ yín múlẹ̀, tí yóo sì pa yín mọ́ kúrò ninu ibi gbogbo.

Ka pipe ipin Tẹsalonika Keji 3

Wo Tẹsalonika Keji 3:3 ni o tọ