9 Kì í ṣe pé a kò ní ẹ̀tọ́ láti jẹun lọ́dọ̀ yín; ṣugbọn a kò ṣe bẹ́ẹ̀ kí á lè fi ara wa ṣe àpẹẹrẹ fun yín, kí ẹ lè fara wé wa.
Ka pipe ipin Tẹsalonika Keji 3
Wo Tẹsalonika Keji 3:9 ni o tọ