16 Kò sí ẹni tí kò mọ̀ pé àṣírí ẹ̀sìn wa jinlẹ̀ pupọ:Ẹni tí ó farahàn ninu ẹran-ara,tí a dá láre ninu ẹ̀mí,tí àwọn angẹli fi ojú rí,tí à ń waasu rẹ̀ láàrin àwọn alaigbagbọ,tí a gbàgbọ́ ninu ayé,tí a gbé lọ sinu ògo.
Ka pipe ipin Timoti Kinni 3
Wo Timoti Kinni 3:16 ni o tọ