Timoti Kinni 5:21 BM

21 Mo sọ fún ọ, níwájú Ọlọrun ati Kristi Jesu, ati àwọn angẹli tí Kristi ti yàn, pé kí o pa ọ̀rọ̀ yìí mọ́; má ṣe ojuṣaaju.

Ka pipe ipin Timoti Kinni 5

Wo Timoti Kinni 5:21 ni o tọ