Timoti Kinni 5:22 BM

22 Má fi ìwàǹwára gbé ọwọ́ lé ẹnikẹ́ni lórí láti fi jẹ oyè ninu ìjọ, má sì di alábàápín ninu ẹ̀ṣẹ̀ ẹlòmíràn. Jẹ́ kí ọwọ́ rẹ mọ́.

Ka pipe ipin Timoti Kinni 5

Wo Timoti Kinni 5:22 ni o tọ