Timoti Kinni 6:7 BM

7 Nítorí a kò mú ohunkohun wá sinu ayé, bẹ́ẹ̀ ni a kò lè mú ohunkohun kúrò ninu rẹ̀.

Ka pipe ipin Timoti Kinni 6

Wo Timoti Kinni 6:7 ni o tọ