Ẹk. Jer 1:16 YCE

16 Emi nsọkun nitori nkan wọnyi; oju mi! oju mi ṣàn omi silẹ, nitoripe olutunu ati ẹniti iba mu ọkàn mi sọji jina si mi: awọn ọmọ mi run, nitoripe ọta bori.

Ka pipe ipin Ẹk. Jer 1

Wo Ẹk. Jer 1:16 ni o tọ