Ẹk. Jer 1:19 YCE

19 Emi pè awọn olufẹ mi, awọn wọnyi tàn mi jẹ: awọn alufa mi, ati àgbagba mi jọwọ ẹmi wọn lọwọ ni ilu, nigbati nwọn nwá onjẹ wọn lati mu ẹmi wọn sọji.

Ka pipe ipin Ẹk. Jer 1

Wo Ẹk. Jer 1:19 ni o tọ