Ẹk. Jer 1:21 YCE

21 Nwọn gbọ́ bi emi ti nkẹdùn to: sibẹ kò si olutunu fun mi: gbogbo awọn ọta mi gbọ́ iyọnu mi; inu wọn dùn nitori iwọ ti ṣe e: iwọ o mu ọjọ na wá ti iwọ ti dá, nwọn o si ri gẹgẹ bi emi.

Ka pipe ipin Ẹk. Jer 1

Wo Ẹk. Jer 1:21 ni o tọ