Ẹk. Jer 1:4 YCE

4 Ọ̀na Sioni wọnni nṣọ̀fọ, nitori ẹnikan kò wá si ajọ-mimọ́: gbogbo ẹnu-bode rẹ̀ dahoro: awọn alufa rẹ̀ kẹdun, awọn wundia rẹ̀ nkãnu, on si wà ni kikoro ọkàn.

Ka pipe ipin Ẹk. Jer 1

Wo Ẹk. Jer 1:4 ni o tọ