Ẹk. Jer 2:14 YCE

14 Awọn woli rẹ ti riran ohun asan ati wère fun ọ: nwọn kò si ti fi aiṣedede rẹ hàn ọ, lati yi igbekun rẹ pada kuro; ṣugbọn nwọn ti riran ọ̀rọ-wiwo eke fun ọ ati imuniṣina.

Ka pipe ipin Ẹk. Jer 2

Wo Ẹk. Jer 2:14 ni o tọ