Ẹk. Jer 2:16 YCE

16 Gbogbo awọn ọta rẹ ya ẹnu wọn si ọ; nwọn nṣe ṣiọ! nwọn si npa ehin keke, nwọn wipe: Awa ti gbe e mì; dajudaju eyi li ọjọ na ti awa ti nwọ̀na fun; ọwọ ti tẹ̀ ẹ, awa ti ri i!

Ka pipe ipin Ẹk. Jer 2

Wo Ẹk. Jer 2:16 ni o tọ