Ẹk. Jer 2:2 YCE

2 Oluwa ti gbe gbogbo ibugbe Jakobu mì, kò si da a si: o ti wó ilu-odi ọmọbinrin Juda lulẹ, ninu irunu rẹ̀ o ti lù wọn bolẹ: o ti sọ ijọba na ati awọn ijoye rẹ̀ di alaimọ́.

Ka pipe ipin Ẹk. Jer 2

Wo Ẹk. Jer 2:2 ni o tọ