Ẹk. Jer 4:10 YCE

10 Ọwọ awọn obinrin alãnu ti sè awọn ọmọ awọn tikarawọn: awọn wọnyi li ohun jijẹ fun wọn ni igba wahala ọmọbinrin awọn enia mi.

Ka pipe ipin Ẹk. Jer 4

Wo Ẹk. Jer 4:10 ni o tọ