Ẹk. Jer 4:6 YCE

6 Nitori aiṣedede ọmọbinrin awọn enia mi tobi jù ẹ̀ṣẹ Sodomu lọ, ti a bì ṣubu ni iṣẹju, laisi iṣiṣẹ ọwọ ninu rẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹk. Jer 4

Wo Ẹk. Jer 4:6 ni o tọ