Ẹk. Jer 5:21 YCE

21 Oluwa, yi wa pada sọdọ rẹ, awa o si yipada; sọ ọjọ wa di ọtun gẹgẹ bi ti igbãni.

Ka pipe ipin Ẹk. Jer 5

Wo Ẹk. Jer 5:21 ni o tọ