Mik 2:9 YCE

9 Obinrin awọn enia mi li ẹnyin ti le jade kuro ninu ile wọn daradara; ẹnyin ti gbà ogo mi kuro lọwọ awọn ọmọ wọn lailai.

Ka pipe ipin Mik 2

Wo Mik 2:9 ni o tọ