Mik 4:5 YCE

5 Nitori gbogbo awọn enia ni yio ma rìn, olukuluku li orukọ ọlọrun tirẹ̀, awa o si ma rìn li orukọ Oluwa Ọlọrun wa lai ati lailai.

Ka pipe ipin Mik 4

Wo Mik 4:5 ni o tọ