O. Sol 1:8 YCE

8 Bi iwọ kò ba mọ̀, Iwọ arẹwà julọ ninu awọn obinrin, jade lọ ni ipasẹ agbo-ẹran, ki iwọ ki o si bọ́ awọn ọmọ ewurẹ rẹ lẹba agọ awọn aluṣọ-agutan.

Ka pipe ipin O. Sol 1

Wo O. Sol 1:8 ni o tọ