O. Sol 7:13 YCE

13 Awọn eso mandraki fun ni li õrùn, li ẹnu-ọ̀na wa ni onirũru eso ti o wunni, ọtun ati ogbologbo, ti mo ti fi pamọ́ fun ọ, iwọ olufẹ mi.

Ka pipe ipin O. Sol 7

Wo O. Sol 7:13 ni o tọ