Gal 4:30 YCE

30 Ṣugbọn iwe-mimọ́ ha ti wi? Lé ẹrú-binrin na jade ati ọmọ rẹ̀: nitori ọmọ ẹrú-binrin kì yio ba ọmọ omnira-obinrin jogun pọ̀.

Ka pipe ipin Gal 4

Wo Gal 4:30 ni o tọ