Heb 1:6 YCE

6 Ati pẹlu, nigbati o mu akọbi ni wá si aiye, o wipe, Ki gbogbo awọn angẹli Ọlọrun ki o foribalẹ fun u.

Ka pipe ipin Heb 1

Wo Heb 1:6 ni o tọ