Heb 10:30 YCE

30 Nitori awa mọ̀ ẹniti o wipe, Ẹsan ni ti emi, Oluwa wipe, Emi o gbẹsan. Ati pẹlu, Oluwa yio ṣe idajọ awọn enia rẹ̀.

Ka pipe ipin Heb 10

Wo Heb 10:30 ni o tọ