Heb 11:3 YCE

3 Nipa igbagbọ́ li a mọ̀ pe a ti da aiye nipa ọ̀rọ Ọlọrun; nitorina ki iṣe ohun ti o hàn li a fi dá ohun ti a nri.

Ka pipe ipin Heb 11

Wo Heb 11:3 ni o tọ