Heb 12:23 YCE

23 Si ajọ nla ati ìjọ akọbi ti a ti kọ orukọ wọn li ọ̀run, ati sọdọ Ọlọrun onidajọ gbogbo enia, ati sọdọ awọn ẹmí olõtọ enia ti a ṣe li aṣepé,

Ka pipe ipin Heb 12

Wo Heb 12:23 ni o tọ