Heb 12:8 YCE

8 Ṣugbọn bi ẹnyin ba wà li aisi ibawi, ninu eyiti gbogbo enia ti jẹ alabapin, njẹ ọmọ àle ni nyin, ẹ kì isi iṣe ọmọ.

Ka pipe ipin Heb 12

Wo Heb 12:8 ni o tọ