Heb 2:11 YCE

11 Nitori ati ẹniti nsọni di mimọ́ ati awọn ti a nsọ di mimọ́, lati ọdọ ẹnikanṣoṣo ni gbogbo wọn: nitori eyiti ko ṣe tiju lati pè wọn ni arakunrin,

Ka pipe ipin Heb 2

Wo Heb 2:11 ni o tọ