Heb 3:4 YCE

4 Lati ọwọ́ enia kan li a sá ti kọ́ olukuluku ile; ṣugbọn ẹniti o kọ́ ohun gbogbo ni Ọlọrun.

Ka pipe ipin Heb 3

Wo Heb 3:4 ni o tọ