Heb 7:13 YCE

13 Nitori ẹniti a nsọ̀rọ nkan wọnyi nipa rẹ̀ jẹ ẹ̀ya miran, lati inu eyiti ẹnikẹni koi jọsin ri nibi pẹpẹ.

Ka pipe ipin Heb 7

Wo Heb 7:13 ni o tọ