1. Tes 2:17 YCE

17 Ṣugbọn, ará, awa ti a gbà kuro lọdọ nyin fun sã kan li ara, ki iṣe li ọkàn, pẹlu itara ọpọlọpọ li awa ṣe aniyan ti a si fẹ gidigidi lati ri oju nyin.

Ka pipe ipin 1. Tes 2

Wo 1. Tes 2:17 ni o tọ