1. Tes 3:13 YCE

13 Ki o ba le fi ọkàn nyin balẹ li ailabukù ninu ìwa mimọ́ niwaju Ọlọrun ati Baba wa, nigba atiwá Jesu Kristi Oluwa wa pẹlu gbogbo awọn enia mimọ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin 1. Tes 3

Wo 1. Tes 3:13 ni o tọ