1. Tes 4:17 YCE

17 Nigbana li a ó si gbà awa ti o wà lãye ti o si kù lẹhin soke pẹlu wọn sinu awọsanma, lati pade Oluwa li oju ọrun: bẹ̃li awa ó si ma wà titi lai lọdọ Oluwa.

Ka pipe ipin 1. Tes 4

Wo 1. Tes 4:17 ni o tọ