1. Tim 1:15 YCE

15 Otitọ li ọrọ na, o si yẹ fun itẹwọgbà, pe Kristi Jesu wá si aiye lati gbà ẹlẹṣẹ là; ninu awọn ẹniti emi jẹ pàtaki.

Ka pipe ipin 1. Tim 1

Wo 1. Tim 1:15 ni o tọ