1. Tim 2:2 YCE

2 Fun awọn ọba, ati gbogbo awọn ti o wà ni ipo giga; ki a le mã lo aiye wa ni idakẹjẹ ati pẹlẹ ninu gbogbo ìwa-bi-Ọlọrun ati ìwa agbà.

Ka pipe ipin 1. Tim 2

Wo 1. Tim 2:2 ni o tọ