1. Tim 4:1 YCE

1 ṢUGBỌN Ẹmí ntẹnumọ ọ pe, ni igba ikẹhin awọn miran yio kuro ninu igbagbọ́, nwọn o mã fiyesi awọn ẹmí ti ntan-ni-jẹ, ati ẹkọ́ awọn ẹmí èṣu;

Ka pipe ipin 1. Tim 4

Wo 1. Tim 4:1 ni o tọ