1. Tim 4:16 YCE

16 Mã ṣe itọju ara rẹ ati ẹkọ́ rẹ; mã duro laiyẹsẹ ninu nkan wọnyi: nitori ni ṣiṣe eyi, iwọ ó gbà ara rẹ ati awọn ti ngbọ́ ọ̀rọ rẹ là.

Ka pipe ipin 1. Tim 4

Wo 1. Tim 4:16 ni o tọ