1. Tim 4:8 YCE

8 Nitori ṣíṣe eré ìdaraya ní èrè diẹ, ṣugbọn ìwa-bi-Ọlọrun li ère fun ohun gbogbo, o ni ileri ti aiye isisiyi ati ti eyi ti mbọ̀.

Ka pipe ipin 1. Tim 4

Wo 1. Tim 4:8 ni o tọ