1. Tim 6:10 YCE

10 Nitori ifẹ owo ni gbòngbo ohun buburu gbogbo: eyiti awọn miran nlepa ti a si mu wọn ṣako kuro ninu igbagbọ́, nwọn si fi ibinujẹ pupọ̀ gún ara wọn li ọ̀kọ̀.

Ka pipe ipin 1. Tim 6

Wo 1. Tim 6:10 ni o tọ