2. Joh 1:3 YCE

3 Õre-ọfẹ, ãnu, ati alafia, yio wà pẹlu wa, lati ọdọ Ọlọrun Baba, ati lati ọdọ Jesu Kristi, Ọmọ Baba, ninu otitọ ati ninu ifẹ.

Ka pipe ipin 2. Joh 1

Wo 2. Joh 1:3 ni o tọ