2. Pet 1:12 YCE

12 Nitorina emi ó mã mura lati mã mu nkan wọnyi wá si iranti nyin nigbagbogbo bi ẹnyin tilẹ ti mọ̀ wọn, ti ẹsẹ nyin si mulẹ ninu otitọ ti ẹnyin ni.

Ka pipe ipin 2. Pet 1

Wo 2. Pet 1:12 ni o tọ