2. Pet 3:18 YCE

18 Ṣugbọn ẹ mã dàgba ninu õre-ọfẹ ati ninu ìmọ Oluwa ati Olugbala wa Jesu Kristi; ẹniti ogo wà fun nisisiyi ati titi lai. Amin.

Ka pipe ipin 2. Pet 3

Wo 2. Pet 3:18 ni o tọ