4 Nwọn o si mã wipe, Nibo ni ileri wíwa rẹ̀ gbé wà? lati igbati awọn baba ti sùn, ohun gbogbo nlọ bi nwọn ti wà rí lati ìgba ọjọ ìwa.
Ka pipe ipin 2. Pet 3
Wo 2. Pet 3:4 ni o tọ