2. Pet 3:7 YCE

7 Ṣugbọn awọn ọrun ati aiye, ti mbẹ nisisiyi, nipa ọ̀rọ kanna li a ti tojọ bi iṣura fun iná, a pa wọn mọ́ dè ọjọ idajọ ati iparun awọn alaiwa-bi-Ọlọrun.

Ka pipe ipin 2. Pet 3

Wo 2. Pet 3:7 ni o tọ