2. Tes 1:4 YCE

4 Tobẹ̃ ti awa tikarawa nfi nyin ṣogo ninu ijọ Ọlọrun, nitori sũru ati igbagbọ́ nyin ninu gbogbo inunibini ati wahalà nyin ti ẹnyin nfarada,

Ka pipe ipin 2. Tes 1

Wo 2. Tes 1:4 ni o tọ