Tit 2:5 YCE

5 Lati jẹ alairekọja, mimọ́, òṣiṣẹ́ nile, ẹni rere, awọn ti ntẹriba fun awọn ọkọ wọn, ki ọrọ Ọlọrun ki o máṣe di isọ̀rọ-òdi si.

Ka pipe ipin Tit 2

Wo Tit 2:5 ni o tọ