Tit 3:15 YCE

15 Gbogbo awọn ti mbẹ lọdọ mi kí ọ. Kí awọn ti o fẹ wa ninu igbagbọ́. Ki ore-ọfẹ ki o wà pẹlu gbogbo nyin. Amin.

Ka pipe ipin Tit 3

Wo Tit 3:15 ni o tọ