15 Jónátanì ọmọ Ásáhélì àti Jáhéséáyà ọmọ Jíkífà nìkan pẹ̀lú àtìlẹyìn Mésísúlámù àti Ṣíábétaì ará Léfì, ni wọ́n tako àbá yìí.
Ka pipe ipin Ẹ́sírà 10
Wo Ẹ́sírà 10:15 ni o tọ