Ẹ́sírà 10:44 BMY

44 Gbogbo àwọn wọ̀nyí ló fẹ́ obìnrin àjèjì, àwọn mìíràn nínú wọn sì bi ọmọ ní ipaṣẹ̀ àwọn ìyàwó wọ̀nyí.

Ka pipe ipin Ẹ́sírà 10

Wo Ẹ́sírà 10:44 ni o tọ