Ẹ́sírà 3:13 BMY

13 Kò sí ẹni tí ó le mọ́ ìyàtọ̀ láàárin igbe ayọ̀ àti ẹkún, nítorí tí ariwo àwọn ènìyàn náà pọ̀ tó bẹ́ẹ̀ gẹ́ẹ́. Wọ́n sì gbọ́ igbe náà ní ọ̀nà jínjìn réré.

Ka pipe ipin Ẹ́sírà 3

Wo Ẹ́sírà 3:13 ni o tọ