Ẹ́sírà 4:10 BMY

10 pẹ̀lú àwọn ènìyàn mìíràn tí ẹni ọlá àti ẹni ọ̀wọ̀ Áṣúríbánípálì lé jáde tí ó sì tẹ̀ wọ́n dó sí ìlú Samáríà àti níbòmíràn ní agbègbè e Yúfúrátè.

Ka pipe ipin Ẹ́sírà 4

Wo Ẹ́sírà 4:10 ni o tọ